Ayaba Alaafin Oyo, Olori Ola ko ile fun iya e
Olori Ola Adeyemi, aya Alaafin Oyo ti o kere ju ti o je omo odun meta din l’ogbon ni odun ti o koja se ko ile fun iya e.
E tun le ka: Awon aworan oye ti ayaba Alaafin oyo ati awon omo re ya
O fi aworan ile naa si ori ero ayelujara (instagram) o si so wipe:
Mummy….. I have always promise to make you happy no matter what… U built a life for me and I build a house for you mum… You went through a lot to gave birth to me… I spent 11months inside ur womb before you gave birth to me…