Skip to content

Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun

Davido ni oro fun awon ti o fi esun iku Tagbo kan oun

Davido ti se afihan wipe oun ko ni ikun sinu kankan si enikeni ti o ro wipe oun ni owo ninu iku Tagbo.
Osere ‘binrin Caroline Danjuma ti o fi esun kan wipe o ni owo ninu iku Tagbo ti o si rii pe o lo si ago olopa, Davido ti won ti tu sile ti jade lati so wipe oun ti dariji awon ti o ni owo ninu iku ore oun ti o di oloogbe.

E tunle ka: Idi ti Odunlade Adekola se pada lati pari eko re

Davido koo si ori ero ayelujara snapchat wipe:

“Thank you Jesus” before calling out “persons that said false things about me or accused me of what I don’t know.

“I sincerely forgive you.. and God bless you. We move on. Let’s all be better. Thank you Lord.”

“Thank you to everyone that prayed for me and to those who didn’t.. Maybe you forgot,” he wrote.

“We thank God all in all. Now lets get back to the music.”