Oro Nla Ti Opeyemi Aiyeola Fi Ki omo Re Ku ojo Ibi
Osere ilumooka Opeyemi aiyeola kuro ni idi sise ere agbelewo Yoruba nigbati o se igbeyawo pelu oko re Olayiwola owolomose ni odun 2017, ti o si fi ibujoko re si US. Ni ojoru, 27th September, Opeyemi aiyeola bo si ori ero abanidore instagram re lati kede ojo ibi omo re Oluwasemilori David ti o pe omo odun mefa ni ojo naa.
E TUN LE KA: Awon Osere Yoruba Ti Won Fera Won, NUMBER 1 MA YA YIN LENU
Opeyemi Aiyeola fi orisirisi aworan han ni ori ero instagram re ti o si ko oro nla nla lati fi ye omo olojoibi si… o ko wipe: