Osere Femi Adebayo ti bo si ori ero abanidore Instagram lati ki iyawo re Aduke ku Ojo Ibi. Ninu atejise naa femi adebayo ki iyawo re ku aduroti, osi so wipe oun nikan ni oun n wo loju, o ni;
Femi Adebayo fe iyawo re Omotayo Sanusi, leyin odun mejo 8yrs ti iyawo re akoko khadijat ko sile lati fe okunrin omiran.