Skip to content

Seun Egbegbe Rerin Jade Kuro Ninu Ogba Ewon O

Alagbata awon ere Yoruba ni Ilu Nigeria ti Oruko re n je ogbeni Seun Egbegbe pelu akegbe re ti won mu wipe won gba awon mola ti o n se owo ni o rerin si kamera awon oniroyin bi o se n jade kuro ninu ogba awon.

Ni ojo eti ni a gbo wipe Ile Ejo agba ti Ijoba, eka ti ilu eko tu Seun Egbegbe ati akegbe re sile pelu Oniduro meji ti won si san 2.5 Million, enikookan.

Justice Oluremi Oguntoyinbo who presided over the case ruled Mr. Seun should be granted bail once he meets bail requirements.

Egbegbe oRISUN TV

“Both accused should be granted bail of N5million with two sureties each in a sum of N2.5million. That is four sureties altogether. One of the sureties must be a civil servant who has attained level 16 while the other surety must be a land owner in any part of Lagos metropolis.”

“The landowner must submit Certificate of Ownership of the landed property and while the civil servant must submit his international passport to the court. The four sureties must swear to an affidavit while the house and office addresses and telephone number will be verified by the court,” she added.

Mr. Seun will be in prison custody pending fulfillment of bail conditions. Mr. Seun and Mr. Ayomide were both arrested for defrauding some Bureau De Change operatives of over N40.647 million between 2016 and February 2017 before he was apprehended by men of the Nigeria Police Force.

E LE RI IROYIN MIRAN KA NIBI: IROYIN