Orisun TV
  • Abawole
  • Iroyin Ni Soki
  • Celebrity Interview
  • Loju Popo
No Result
View All Result
  • Abawole
  • Iroyin Ni Soki
  • Celebrity Interview
  • Loju Popo
No Result
View All Result
Orisun TV
No Result
View All Result

Omo Chibok Miran Ni Awon Ologun Ile Wa Tun Ti Gba Pada

orisun by orisun
06/01/2017
in Orisun
0
0
SHARES
54
VIEWS
Share on FacebookShare on Twitter

Omo chibok miran ni a tun ti gbo wipe won ri gba lowo awon omo ogun Iko Boko Haram pelu omo kekere ti o bi.

Awon Omo ogun Ile Nigeria ti fi idi re mule pe won ti ri omo Chibok miran ti won gbe lojo kinni ana.

RelatedPosts

#DTT: Ayeye Ojo Ibi Oga Agba Ile Ise Orisun Ogbeni Femi Aderibigbe (Kwame)

#DTT: Ayeye Ojo Ibi Oga Agba Ile Ise Orisun Ogbeni Femi Aderibigbe (Kwame)

#DTT: Oku Sound Sultan Wo Kaa Ile Lo

#DTT: Oku Sound Sultan Wo Kaa Ile Lo

#FidioTitun: Danny S – Oh My God

Gege bi ati gbo lenu aimoye eniyan, awon Omo ogun wa ri omo naa ni inu igbo Alargano ni ilu Borno nigbati awon omo ogun ti Lafiya Dole gba ibe koja.

Siwaju sii, Oga awon Alukoro fun Awon Ologun Ile wa, Ogagun Sani Usman so wipe awon yoo gbe iroyin miran to ba jeyo jade laipe.

Ninu Oro re, o wipe “Awon Omo ogun wa ti ri omo ileewe chibok miran. A o gbe Iroyin Lekunrere jade laipe,”  Beeni o tun wipe “Awon omo ogun ti eka Lafiya Dole nigbati won n se iwadi fura pe awon omo Iko Boko Haram fi okan lara awon omo chibok naa pamo ti oruko re si n je Rakiya Abubakar pelu omo owo ti ko tii ju osu mefa lo.chibok

Tags: alaroyeChibokchibok girlsGovernmentNigerian ArmyOmo OgunPunchpunchngRakiya abubakarsani usmanShekau
Previous Post

Ronaldo Da Da Eebu ti Kroos Pada Lori Twitter

Next Post

Riyad Mahrez Ni Won Fun Ni Ami Eye Agbaboolu To Dangajiya Ju Ti CAF

Related Posts

#DTT: Ayeye Ojo Ibi Oga Agba Ile Ise Orisun Ogbeni Femi Aderibigbe (Kwame)
Orisun

#DTT: Ayeye Ojo Ibi Oga Agba Ile Ise Orisun Ogbeni Femi Aderibigbe (Kwame)

#DTT: Oku Sound Sultan Wo Kaa Ile Lo
Orisun

#DTT: Oku Sound Sultan Wo Kaa Ile Lo

Orisun

#FidioTitun: Danny S – Oh My God

Orisun

Orin Titun: Zlatan – Ijaya

Aare Ko Tun Ni Dije Dupo Mo Ni Odun 2023 | Iroyin Lori Orisun
Orisun

Aare Ko Tun Ni Dije Dupo Mo Ni Odun 2023 | Iroyin Lori Orisun

Awon Ara Ilu Rawo Ebe Si Ijoba Ipinle Eko Lati Bawon Tu Ona Won Se | Iroyin Lori Orisun
Orisun

Awon Ara Ilu Rawo Ebe Si Ijoba Ipinle Eko Lati Bawon Tu Ona Won Se | Iroyin Lori Orisun

Next Post
riyad

Riyad Mahrez Ni Won Fun Ni Ami Eye Agbaboolu To Dangajiya Ju Ti CAF

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

  • KINI NKAN TI A N PE NI IGBAGBO?

    KINI NKAN TI A N PE NI IGBAGBO?

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • Bi Won Se N Se Eto Igbeyawo Ni Ile Yoruba

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • YORUBA TRADITION, VALUES & HERITAGE – IYA ASA

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • BI A SE LE FI EEDU WO ARUN ARA

    0 shares
    Share 0 Tweet 0
  • #OrisunAtTen: Ayandigold Se Bebe Ni Ayeye Odun Kewa Orisun

    0 shares
    Share 0 Tweet 0

© 2022 Virtual Media Network LTD

No Result
View All Result
  • Abawole
  • Iroyin Ni Soki
  • Celebrity Interview
  • Loju Popo

© 2022 Virtual Media Network LTD