Skip to content

2face yan tiwa Savage Gegebi Olukorin Keji fun Buckwyld ‘n’ Breathless concert

Leyin igba ti ayeye Buckwyld ‘n’ Breathless Disruption concert ti won se ni 2016 yege, 2face ti fi han gbogbo aye pe eleekeji ayeye Buckwyld ‘n’ Breathless ti won pe ni ‘The Lagos Dream’ ma waye ni Convention Centre, Eko Hotels ni 22nd of October, 2017.

buckwyld-tiwa-2face-orisun

2face idibia, ti o je olukorin Akoko fun ayeye Buckwyld ‘n’ Breathless ti yan akorin egbe re obirin Tiwa Savage gegebi olukorin keji fun eto naa ti ayeye yi maa kun fun awon olorin jankan jankan;  ‘The concert will be packed with world class live performances featuring many A-list artistes. I assure you, it will be different from what fans are used to”.