Olorin Dammy Krane ti pada si eko fun igba die leyin nkan ti oju e ri ni ewon ni Miami,usa. Olorin ti o ko “Amin” ti awon olopa daaduro ni us fun opolopo esun ti ole ati credit card fraud pelu awon esun ti won fi kan ti royin nipa nkan ti oju re ri ni ewon.
E TUN LE KA: Ipe lati odo olorun ni atimole mi je”- Dammy Krane
Ninu iforowanilenu wo naa, Dammy Krane so wipe eeyan die ni o gba oun gbo ti o si duro ti oun nigba ti oun fi ojuba ile ejo. O so wipe yato si awon ebi oun, die ninu awon ti awon jo n korin ni o duri ti oun; “My family was there for me and my other family”.
Nigba ti won bi wipe awon won i ebi re keji, o dahun pe Davido ati 2face nikan lo duro fun oun. O so ninu iforowanilenu wo naa pe, awon ti o gba oun gbo tabi duro ti oun oun o ni nkan so siwo; “I don’t even know them”.
Dammy Krane tun soro siwaju si lori nkan ti oju re ri ni ewon, o so wipe oun moomoo da wbi pa ara oun nitori oun o le je ounje tutu ti won fun oun ni ogba ewon, “We were given cold rice, a piece of cookie an orange daily, I ate only the cookie and the orange”