Sunday, September 20, 2020

Ijiroro Pelu Idile Akinwunmi King Lori Ile Alayo Pelu Ola Onabajo

Lori Eto Ile Alayo Pelu Ola Onabajo, Idile Akinwunmi King Ni Alejo wa fun ojo oni, Awon Ijiroro Pataki ati awon ohun ti o...

Egbe Oselu APC Jawe Olubori Ninu Idibo Ibile To Waye Ni...

Egbe Oselu APC ti jawe Olubori Ninu Idibo Ibile to waye ni ipinle Ondo, ekunrere iroyin naa re.  

Awon Merin Lo Papoda Ninu Ijamba Oko To Waye Ni Ilu...

Awon Merin Lo Papoda Ninu ijamba oko eyi to o sele ni Ilu Epe, Iroyin Lekunrere naa re 

#RevolutionNow: Awon Olopa Gbegi Dina Awon Olufehonuhan Lori Bi Ohun Gbogbo...

Awon Olopa Gbegi dina Awon ti o nfehonuhan Lori bi ohun gbogbo se nlo lorile ede nigeria. Ekunrere Iroyin Naa Re 

Korede Bello Gba Awon Odo N’Imoran Lati Mu Arawon Ni Pataki

Gbajugbaja Olorin, Korede Bello ti gba awon odo ni imoran lati mu awa won ni pataki ni ikorita orin ati amuludun E gbo ekunrere oro...

Gbajumo Osere Sinima Ijebu So Bi Aye Re Seri

Gbajumo Osere, Tayo Amokade, eyi ti gbogbo eniyan mo si Ijebu So Bi Aye re seri ki O to di ilumooka, Bawo Ni O Se...

Ẹṣe Alabapin Ninu Iroyin Wa

Lati Gba Awọn Iroyin Wa Ninu Imeeli Yin